Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 50:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Josẹfu sin òkú baba rẹ̀ tán, ó pada lọ sí ilẹ̀ Ijipti pẹlu àwọn arakunrin rẹ̀, ati gbogbo àwọn tí wọ́n bá a lọ.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 50

Wo Jẹnẹsisi 50:14 ni o tọ