Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 49:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jakọbu parí ìkìlọ̀ tí ó ń ṣe fún àwọn ọmọ rẹ̀, ó ká ẹsẹ̀ rẹ̀ pada sí orí ibùsùn rẹ̀, ó dùbúlẹ̀, lẹ́yìn náà ó mí kanlẹ̀, ó sì re ibi tí àgbà á rè.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 49

Wo Jẹnẹsisi 49:33 ni o tọ