Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 49:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun baba rẹ yóo ràn ọ́ lọ́wọ́.Ọlọrun Olodumare yóo rọ òjò ibukun sórí rẹ láti òkè ọ̀run wá,yóo sì fún ọ ní ibukun omi tí ó wà ní ìsàlẹ̀ ilẹ̀,ati ọpọlọpọ ọmọ ati ọpọlọpọ ẹran ọ̀sìn.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 49

Wo Jẹnẹsisi 49:25 ni o tọ