Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 49:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu ranṣẹ pe àwọn ọmọ rẹ̀, ó wí fún wọn pé, “Ẹ kó ara yín jọ kí n lè sọ ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ si yín ní ọjọ́ iwájú fún yín.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 49

Wo Jẹnẹsisi 49:1 ni o tọ