Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 48:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí Israẹli na ọwọ́ rẹ̀ láti súre fún wọn, ó dábùú ọwọ́ rẹ̀ lórí ara wọn, ó gbé ọwọ́ ọ̀tún lé Efuraimu lórí, ó sì gbé ọwọ́ òsì lé Manase lórí, bẹ́ẹ̀ ni Efuraimu ni àbúrò, Manase sì ni àkọ́bí.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 48

Wo Jẹnẹsisi 48:14 ni o tọ