Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 47:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá kó àwọn ẹran ọ̀sìn wọn tọ Josẹfu lọ, Josẹfu sì fún wọn ní oúnjẹ dípò àwọn ẹran ọ̀sìn wọn, agbo ẹran wọn, agbo mààlúù wọn ati kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọn. Ó fi àwọn ẹran ọ̀sìn wọn dí oúnjẹ fún wọn ní ọdún náà.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 47

Wo Jẹnẹsisi 47:17 ni o tọ