Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 46:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ilé rẹ̀ patapata ni Jakọbu kó lọ́wọ́ lọ sí Ijipti, ati àwọn ọmọ rẹ̀, ati àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀, lọkunrin ati lobinrin, gbogbo wọn ni ó kó lọ sí Ijipti patapata.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 46

Wo Jẹnẹsisi 46:7 ni o tọ