Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 46:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu bá bẹ̀rẹ̀ ìrìn àjò rẹ̀ láti Beeriṣeba. Àwọn ọmọ rẹ̀ gbé e sinu ọkọ̀ tí Farao fi ranṣẹ sí i pé kí wọ́n fi gbé e wá, wọ́n sì kó àwọn iyawo wọn ati àwọn ọmọ wọn lọ́wọ́ pẹlu wọn.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 46

Wo Jẹnẹsisi 46:5 ni o tọ