Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 46:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu bọ́ sinu kẹ̀kẹ́ ẹlẹ́ṣin rẹ̀, ó lọ pàdé Israẹli, baba rẹ̀ ní Goṣeni. Nígbà tí Josẹfu dé ọ̀dọ̀ baba rẹ̀, ó rọ̀ mọ́ ọn lọ́rùn, ó sì sọkún fún ìgbà pípẹ́.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 46

Wo Jẹnẹsisi 46:29 ni o tọ