Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 45:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fún olukuluku wọn ní ìpààrọ̀ aṣọ kọ̀ọ̀kan, ṣugbọn ó fún Bẹnjamini ní ọọdunrun (300) ṣekeli fadaka ati ìpààrọ̀ aṣọ marun-un.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 45

Wo Jẹnẹsisi 45:22 ni o tọ