Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 44:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọn kò tíì rìn jìnnà sí ìlú, Josẹfu sọ fún alabojuto ilé rẹ̀ pé, “Gbéra, sáré tẹ̀lé àwọn ọkunrin náà, nígbà tí o bá bá wọn, wí fún wọn pé, ‘Èéṣe tí ẹ fi fi ibi sú olóore? Èéṣe tí ẹ fi jí ife fadaka ọ̀gá mi?

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 44

Wo Jẹnẹsisi 44:4 ni o tọ