Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 44:31 BIBELI MIMỌ (BM)

bí kò bá rí i pẹlu wa, kíkú ni yóo kú. Yóo sì wá jẹ́ pé àwa ni a fa ìbànújẹ́ fún baba wa, ní ọjọ́ ogbó rẹ̀, ìbànújẹ́ yìí ni yóo sì pa á.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 44

Wo Jẹnẹsisi 44:31 ni o tọ