Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 44:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Iranṣẹ náà bá bẹ̀rẹ̀ sí wo àpò wọn, ó bẹ̀rẹ̀ lórí àpò èyí àgbà patapata, títí dé orí ti àbíkẹ́yìn wọn, wọ́n bá ife náà ninu ẹrù Bẹnjamini.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 44

Wo Jẹnẹsisi 44:12 ni o tọ