Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 43:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu bá yára jáde kúrò lọ́dọ̀ wọn nítorí pé ọkàn rẹ̀ fà sí àbúrò rẹ̀, orí rẹ̀ sì wú, ó wá ibìkan láti lọ sọkún. Ó bá wọ yàrá rẹ̀, ó lọ sọkún níbẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 43

Wo Jẹnẹsisi 43:30 ni o tọ