Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 42:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu wá ranti àlá rẹ̀ tí ó lá nípa wọn, ó sì wí fún wọn pé, “Amí ni yín, ibi tí àìlera ilẹ̀ yìí wà ni ẹ wá yọ́ wò.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 42

Wo Jẹnẹsisi 42:9 ni o tọ