Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 42:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ rán ọ̀kan ninu yín kí ó lọ mú àbíkẹ́yìn yín wá, ẹ̀yin yòókù ẹ óo wà ninu ẹ̀wọ̀n títí a óo fi mọ̀ bóyá òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ yín, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, mo tún fi orúkọ Farao búra, amí ni yín.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 42

Wo Jẹnẹsisi 42:16 ni o tọ