Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 41:49 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni Josẹfu ṣe kó ọkà jọ jantirẹrẹ bíi yanrìn etí òkun. Nígbà tó yá, òun gan-an kò mọ ìwọ̀n ọkà náà mọ́, nítorí pé ó ti pọ̀ kọjá wíwọ̀n.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41

Wo Jẹnẹsisi 41:49 ni o tọ