Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 41:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí wọ́n kó gbogbo oúnjẹ wọnyi jọ ninu ọdún tí oúnjẹ yóo pọ̀, kí wọ́n sì kó wọn pamọ́ sinu àwọn ìlú ńláńlá, pẹlu àṣẹ kabiyesi, kí wọ́n sì máa ṣọ́ ọ.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41

Wo Jẹnẹsisi 41:35 ni o tọ