Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 41:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó rí àwọn mààlúù meje kan tí wọ́n sanra rọ̀pọ̀tọ̀ rọ̀pọ̀tọ̀, tí ara wọ́n sì ń dán, wọ́n ti inú odò náà jáde wá, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí jẹ koríko létí odò.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41

Wo Jẹnẹsisi 41:2 ni o tọ