Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 41:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Farao sọ fún un pé, “Mo lá àlá kan, kò sì tíì sí ẹni tí ó lè túmọ̀ rẹ̀. Wọ́n bá sọ fún mi pé, bí o bá gbọ́ àlá, o óo lè túmọ̀ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41

Wo Jẹnẹsisi 41:15 ni o tọ