Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 40:21-23 BIBELI MIMỌ (BM)

21. Ó dá agbọ́tí pada sí ipò rẹ̀ láti máa gbé ọtí fún un,

22. ṣugbọn ó pàṣẹ kí wọ́n lọ so olórí alásè kọ́ igi, gẹ́gẹ́ bí Josẹfu ti túmọ̀ àlá wọn fún wọn.

23. Ṣugbọn olórí agbọ́tí kò ranti Josẹfu mọ, ó gbàgbé rẹ̀ patapata.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 40