Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 40:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé jíjí ni wọ́n jí mi gbé kúrò ní ilẹ̀ Heberu, ati pé níhìn-ín gan-an, kò sí ẹ̀ṣẹ̀ tí mo ṣẹ̀ tí wọ́n fi gbé mi jù sẹ́wọ̀n yìí.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 40

Wo Jẹnẹsisi 40:15 ni o tọ