Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 39:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ó rí ojurere Pọtifari. Pọtifari mú un sọ́dọ̀ pé kí ó máa ṣe iranṣẹ fún òun, ó fi ṣe alabojuto gbogbo ilé rẹ̀, ó sì fi ohun gbogbo tí ó ní sí ìkáwọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 39

Wo Jẹnẹsisi 39:4 ni o tọ