Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 37:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Israẹli sọ fún un pé, “Jọ̀wọ́, lọ bá mi wo alaafia àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ ati ti àwọn agbo ẹran wá, kí o sì tètè pada wá jíṣẹ́ fún mi.” Israẹli bá rán an láti àfonífojì Heburoni lọ sí Ṣekemu.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 37

Wo Jẹnẹsisi 37:14 ni o tọ