Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 36:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó ṣe, Esau kó àwọn aya rẹ̀, àwọn ọmọ rẹ̀ lọkunrin ati lobinrin, gbogbo àwọn ará ilé rẹ̀, àwọn mààlúù rẹ̀, àwọn ẹran ọ̀sìn rẹ̀, ati gbogbo ohun ìní rẹ̀ tí ó ti kójọ ní ilẹ̀ Kenaani, ó kó kúrò ní ilẹ̀ Kenaani lọ́dọ̀ Jakọbu, arakunrin rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 36

Wo Jẹnẹsisi 36:6 ni o tọ