Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 36:38-43 BIBELI MIMỌ (BM)

38. Nígbà tí Ṣaulu kú, Baali Hanani, ọmọ Akibori gorí oyè.

39. Nígbà tí Baali Hanani ọmọ Akibori kú, Hadadi gorí oyè, orúkọ ìlú tirẹ̀ ni Pau, orúkọ aya rẹ̀ ni Mehetabeli, ọmọ Matiredi, ọmọbinrin Mesahabu.

40. Orúkọ àwọn ìjòyè tí wọ́n ṣẹ̀ lára Esau nìwọ̀nyí, gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn ati ìlú tí olukuluku ti jọba: Timna, Alfa, Jeteti,

41. Oholibama, Ela, Pinoni,

42. Kenasi, Temani, Mibisari,

43. Magidieli ati Iramu. Àwọn ni ìjòyè ní Edomu, gẹ́gẹ́ bí ìlú wọn ní ilẹ̀ ìní wọn, Esau tí àdàpè rẹ̀ ń jẹ́ Edomu sì ni baba àwọn ará Edomu.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 36