Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 35:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí Silipa, iranṣẹbinrin Lea bí ni: Gadi ati Aṣeri. Àwọn wọnyi ni àwọn ọmọ tí wọ́n bí fún Jakọbu ní Padani-aramu.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 35

Wo Jẹnẹsisi 35:26 ni o tọ