Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 35:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu bá sọ fún gbogbo àwọn ará ilé rẹ̀ ati àwọn alábàágbé rẹ̀, pé, “Ẹ kó gbogbo ère oriṣa tí ń bẹ lọ́dọ̀ yín dànù, kí ẹ ya ara yín sí mímọ́, kí ẹ sì pààrọ̀ aṣọ yín.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 35

Wo Jẹnẹsisi 35:2 ni o tọ