Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 34:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ará ìlú náà gba ohun tí Hamori ati Ṣekemu ọmọ rẹ̀ wí, gbogbo ọkunrin sì kọlà abẹ́.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 34

Wo Jẹnẹsisi 34:24 ni o tọ