Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 33:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá bèèrè, ó ní, “Kí ni o ti fẹ́ ṣe gbogbo àwọn agbo ẹran tí mo pàdé lọ́nà?” Jakọbu dáhùn, ó ní, “Mo ní kí n fi wọ́n wá ojurere Esau, oluwa mi ni.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 33

Wo Jẹnẹsisi 33:8 ni o tọ