Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 32:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ fún wọn pé, “Ohun tí ẹ óo sọ fún Esau, oluwa mi nìyí, ẹ ní èmi, Jakọbu iranṣẹ rẹ̀, ní kí ẹ sọ fún un pé mo ti ṣe àtìpó lọ́dọ̀ Labani, ati pé ibẹ̀ ni mo sì ti wà títí di àkókò yìí.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 32

Wo Jẹnẹsisi 32:4 ni o tọ