Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 32:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni ó wí pé, “Jẹ́ kí n lọ nítorí ilẹ̀ ti ń mọ́” Ṣugbọn Jakọbu kọ̀, ó ní, “N kò ní jẹ́ kí o lọ, àfi bí o bá súre fún mi.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 32

Wo Jẹnẹsisi 32:26 ni o tọ