Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 32:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jakọbu rí wọn, ó ní, “Àwọn ọmọ ogun Ọlọrun nìyí.” Ó bá sọ ibẹ̀ ní Mahanaimu.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 32

Wo Jẹnẹsisi 32:2 ni o tọ