Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 31:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Fún ogún ọdún tí mo fi bá ọ gbé, ewúrẹ́ rẹ kan tabi aguntan kan kò sọnù rí, bẹ́ẹ̀ ni n kò jí àgbò rẹ kan pajẹ rí.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 31

Wo Jẹnẹsisi 31:38 ni o tọ