Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 31:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Labani lé Jakọbu bá níbi tí ó pàgọ́ rẹ̀ sí ní orí òkè náà, Labani ati àwọn ìbátan rẹ̀ sì pàgọ́ tiwọn sí agbègbè olókè Gileadi.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 31

Wo Jẹnẹsisi 31:25 ni o tọ