Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 30:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹran náà ń gun ara wọn níwájú àwọn ọ̀pá wọnyi, wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí bí ọmọ tí àwọ̀ wọn dàbí adíkálà ati àwọn tí wọ́n ní funfun tóótòòtóó.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 30

Wo Jẹnẹsisi 30:39 ni o tọ