Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 30:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Labani bá bi í léèrè pé, “Kí ni kí n máa fún ọ?” Jakọbu dáhùn pé, “Má fún mi ní ohunkohun, bí o bá gbà láti ṣe ohun kan fún mi, n óo tún máa bá ọ tọ́jú àwọn agbo ẹran rẹ.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 30

Wo Jẹnẹsisi 30:31 ni o tọ