Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 30:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Rakẹli bá dáhùn, ó ní, “Biliha, iranṣẹbinrin mi nìyí, bá a lòpọ̀, kí ó bímọ sí mi lọ́wọ́, kí èmi náà sì lè ti ipa rẹ̀ di ọlọ́mọ.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 30

Wo Jẹnẹsisi 30:3 ni o tọ