Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 30:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí àwọn aya ati àwọn ọmọ mi máa bá mi lọ, nítorí wọn ni mo ṣe sìn ọ́. Jẹ́ kí n máa lọ, ìwọ náà ṣá mọ̀ bí mo ti sìn ọ́ tó.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 30

Wo Jẹnẹsisi 30:26 ni o tọ