Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 3:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ojú àwọn mejeeji bá là, wọ́n sì mọ̀ pé ìhòòhò ni àwọn wà, wọ́n bá gán ewé ọ̀pọ̀tọ́ pọ̀, wọ́n sán an mọ́ ìdí.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 3

Wo Jẹnẹsisi 3:7 ni o tọ