Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 3:3 BIBELI MIMỌ (BM)

àfi igi tí ó wà láàrin ọgbà nìkan ni Ọlọrun ní a kò gbọdọ̀ jẹ ninu èso rẹ̀, a kò tilẹ̀ gbọdọ̀ fọwọ́ kàn án, ati pé ọjọ́ tí a bá fọwọ́ kàn án ni a óo kú.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 3

Wo Jẹnẹsisi 3:3 ni o tọ