Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 3:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, OLUWA Ọlọrun wí pé, “Nisinsinyii tí ọkunrin náà ti dàbí wa, tí ó sì ti mọ ire yàtọ̀ sí ibi, kí ó má lọ mú ninu èso igi ìyè, kí ó jẹ ẹ́, kí ó sì wà láàyè títí lae.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 3

Wo Jẹnẹsisi 3:22 ni o tọ