Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 29:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí OLUWA rí i pé Jakọbu kò fẹ́ràn Lea, ó fún Lea ní ọmọ bí, ṣugbọn Rakẹli yàgàn.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 29

Wo Jẹnẹsisi 29:31 ni o tọ