Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 28:21-22 BIBELI MIMỌ (BM)

21. tí mo bá sì pada dé ilé baba mi ní alaafia, OLUWA ni yóo máa jẹ́ Ọlọrun mi.

22. Òkúta tí mo sì gbé nàró bí ọ̀wọ̀n yìí yóo di ilé Ọlọrun, n óo sì fún ìwọ Ọlọrun ní ìdámẹ́wàá ohun gbogbo tí o bá fún mi.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 28