Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 28:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ rẹ yóo pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀, o óo sì gbilẹ̀ káàkiri sí ìhà ìwọ̀ oòrùn ati sí ìhà ìlà oòrùn, sí ìhà àríwá ati sí ìhà gúsù nípasẹ̀ rẹ ati àwọn ọmọ rẹ ni n óo bukun aráyé.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 28

Wo Jẹnẹsisi 28:14 ni o tọ