Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 28:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó sùn, ó lá àlá kan, ó rí àkàsọ̀ kan lójú àlá, wọ́n gbé e kalẹ̀, orí rẹ̀ kan ojú ọ̀run. Ó wá rí i tí àwọn angẹli Ọlọrun ń gùn ún lọ sókè sódò.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 28

Wo Jẹnẹsisi 28:12 ni o tọ