Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 27:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn wọ́n sọ ohun tí Esau, àkọ́bí Rebeka ń wí fún Rebeka ìyá rẹ̀. Rebeka bá ranṣẹ pe Jakọbu, ó wí fún un pé, “O jẹ́ mọ̀, Esau ẹ̀gbọ́n rẹ ń dá ara rẹ̀ lọ́kàn le pẹlu ìpinnu láti pa ọ́.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 27

Wo Jẹnẹsisi 27:42 ni o tọ