Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 27:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Esau bẹ̀rẹ̀ sí bẹ baba rẹ̀ pé, “Ṣé ìre kan ṣoṣo ni o ní lẹ́nu ni, baba mi? Áà! Súre fún èmi náà, baba mi.” Esau bá bẹ̀rẹ̀ sí sọkún.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 27

Wo Jẹnẹsisi 27:38 ni o tọ