Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 27:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Isaaki bá wí tìfura-tìfura pé, “Súnmọ́ mi, kí n fọwọ́ kàn ọ́, kí n lè mọ̀ bóyá Esau ọmọ mi ni ọ́ lóòótọ́.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 27

Wo Jẹnẹsisi 27:21 ni o tọ