Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 27:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìyá rẹ̀ dá a lóhùn pé, “Kí ègún náà wá sí orí mi, ọmọ mi, ṣá gba ohun tí mo wí, kí o sì lọ mú àwọn ewúrẹ́ náà wá.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 27

Wo Jẹnẹsisi 27:13 ni o tọ